Ni orúkọ Allāh Oba Àjọkẹ Ayé Àṣàkẹ Ọrun
Al-Imām Abū Muḥammad ʿAbdurRahmān ọmọ Abū Ḥātim sọ wípé:
Mo bi Bàbá mi àti Abū Zurʿah ki Allāh yọnu sí àwọn méjèèjì, nípa àwọn ojúpọnà àwọn Ahl As-Sunnah níbi àwọn òfin ìpìnlẹ ẹsìn àti oun tí àwọn méjèèjì bá pàdé ni ọdọ àwọn oní mímọ ẹsìn ní gbogbo ìlú àti oun tí àwọn méjèèjì ni—ni àdìsọkàn nípa eléyìí. Àwọn méjèèjì si sọ wípé:
Read below or download eBook PDF here.
Download here