Àwọn Òfin Ìpìlẹ̀ Sunnah Ti Al Imām Aḥmad ọmọ Ḥanbal
Ní Orúkọ Ọlọhun, Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́Ọ̀run. Al-Imām Aḥmad ọmọ Ḥanbal kí Ọlọhun kẹ́ wọn sọ wípé: Àwọn òfin ìpìlẹ̀ Sunnah ni ọ̀dọ wa, òhun ni gbígbá ohun ti awọn Ṣaḥābah òjíṣẹ́Ọlọhun ﷺwa lórí rẹ̀ mú, àti títẹ̀lé wọn — ni tii àwòkọ́ṣe, àti gbígbé Bidʿah— ìyẹn àdádáálẹ̀ jù sílẹ̀ , àti pé, gbogbo bidʿah jẹ anù. Read below or download eBook PDF here. Download here