Ní orúkọ Allāh Ọba Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́ Ọ̀run.
Nínú àwọn oun to fin jọ ni loju jùlọ, ti o sí jẹ àwọn àmì tó fin tóbi jùlọ, ton tọ́ka sí agbára ọba Olùborí, ni àwọn Ìpìnlẹ̀ mẹ́fà ti Allāh tó ga jùlọ ṣe àlàyé rẹ, ni àlàyé ti o ye yékéyéké fun gbogbo èèyàn, ti o kọjá oun ti àwọn ènìyàn nro.
Read below or download the eBook PDF from here
Download here