Àwọn Ìpìlẹ̀ Mẹ́ta Àti Àwọn Ẹ̀rí í Wọn
Ní orúkọ Ọlọ́hun Àjọkẹ́ ayé Àṣàkẹ́ ọ̀run, Mọ̀, kí Ọlọ́hun kẹ́ ọ, ó ṣe ọ̀ranyàn fún wa láti mọ àwọn àkòrí ọ̀rọ̀ mẹ́rin: Alákọ̀ọ́kọ́: Ìmọ̀, òun náà ni ìmọ̀ Ọlọ́hun, ìmọ̀ Ànọ́bì irẹ̀ àti ìmọ̀ ẹ̀sìn Islām pẹ̀lú àwọn ẹ̀rí. Read below or download the eBook PDF from here Download here