Tag: Story

A Warning Against Nayif Aṣ-Ṣaḥafī And Manṣūr As-Sālimī | Shaykh Abū Sulaymān Fuʾād Ibn Aḥmad Ibn ʿĪsā Az-Zintānī

https://youtu.be/SNbQZ-ILc8M Shaykh Abū Sulaymān Fuʾād Ibn Aḥmad Ibn ʿĪsā Az-Zintānī Abū Nūḥ Al-ʿIrāqī says: There are two individuals with the names Nāyif Aṣ-Ṣaḥafī and Manṣūr As-Sālimī, and many people have been deceived by them. They are storytellers who tell stories such as the repentance of some people from their sins and weak ḥadīths. And they sit with people of innovations such as Al-Maghāmisī and they ...

Read more

Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Láti inú Ìtàn Ikú Abu Tālib, Ẹ̀gbọ́n Bàbá Ànnábí (ﷺ)

Abū Tālib jẹ́ ẹ̀gbọ́n bàbá Ànnábì ﷺ, tí ó sì nífẹ Ànnábi ﷺ lọ́pọ̀lọpọ̀. Nígbàtí àsìkò ikú Abū Tālib tó, Ànnábi ﷺ lọ sí ọ̀dọ rẹ̀ láti pè wípé kí ó gba Islam kí ó tó kú, Ànnábi sọ fun wípé, “Ìrẹ ẹ̀gbọ́n bàbá mi, sọ wípé “Lā ilāha illa Llāh”, ọ̀rọ̀ tí màá fi ṣe ẹ̀rí fún ọ ní iwájú Allāh”. Ṣùgbọ́n kàkàkí Abū ...

Read more

Categories

Donations

Help our organization by donating today! All donations go directly to making a difference for our cause.