Tag: Usool us Sittah

Àwọn Ìpìnlẹ̀ Mẹ́fà

Ní orúkọ Allāh Ọba Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́ Ọ̀run. Nínú àwọn oun to fin jọ ni loju jùlọ, ti o sí jẹ àwọn àmì tó fin tóbi jùlọ, ton tọ́ka sí agbára ọba Olùborí, ni àwọn Ìpìnlẹ̀ mẹ́fà ti Allāh tó ga jùlọ ṣe àlàyé rẹ, ni àlàyé ti o ye yékéyéké fun gbogbo èèyàn, ti o kọjá oun ti àwọn ènìyàn nro. Read below or ...

Read more

Categories

Donations

Help our organization by donating today! All donations go directly to making a difference for our cause.