Ní Orúkọ Ọlọhun, Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́Ọ̀run.
Al-Imām Aḥmad ọmọ Ḥanbal kí Ọlọhun kẹ́ wọn sọ wípé:
Àwọn òfin ìpìlẹ̀ Sunnah ni ọ̀dọ wa, òhun ni gbígbá ohun ti awọn Ṣaḥābah òjíṣẹ́Ọlọhun ﷺwa lórí rẹ̀ mú, àti títẹ̀lé wọn — ni tii àwòkọ́ṣe, àti gbígbé Bidʿah— ìyẹn àdádáálẹ̀ jù sílẹ̀ , àti pé, gbogbo bidʿah jẹ anù.
Read below or download eBook PDF here.
Download here