Ni orúkọ Allāh, Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́Ọ̀run.
Àwọn òfin ìpìlẹ̀ Sunnah ti Imām Al-Ḥumaydi
Bishr bn Mūsá gba wá fun wa, ó sọ pé: Al-Ḥumaydi gba wá fun wa, ó sọ pé:
Sunnah ni ọdọ wa, òhun ni ki èèyàn gbàgbọ́ ninu kádàrá—dáadáa rẹ̀, àti búburú rẹ— dídùn rẹ, àti kíkorò rẹ. Ki o si mọ pé, ohun ti o ba ba, kòsí làkọsílẹ̀ pé yóò tàsé rẹ, ohun tó bá sì tàsé rẹ, kòsí làkọsílẹ̀ pé yóò bá. Àti pé, gbogbo eléyìí jẹ ninu àṣẹ Allāh جل جلاله.
Read below or download eBook PDF here.
Download here