Ni Orúkọ Allāh, Ọba ÀjọkẹAyé, ÀṣàkẹỌrun.
Mọ nbẹ Allāh, Ọba Ọlọrẹ jùlọ, Ọba alága ọlá to kànkà, ki o mu ọ ni ààyò ni ilé ayé nbi àti ni ọjọ ìkẹyìn, àti wípé ki o ṣe ọ ni oníbùkún ni gbogbo ibí tí o ba wa.
Àti wípé ki ó ṣe ọ ni ẹni tí wọn ba fun ni nkan, ti yíò dupẹ, ti wọn ba daan wo, yíò ni sùúrù, ti o ba dẹṣẹ, yíò tọrọ àforíjì. Torí wípé, dajudaju mẹtẹẹta yii jẹ àpẹẹrẹ oríire.
Read below or download the eBook PDF from here
Download here