Tag: yoruba

Àwọn Ìpìnlẹ̀ Mẹ́fà

Ní orúkọ Allāh Ọba Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́ Ọ̀run. Nínú àwọn oun to fin jọ ni loju jùlọ, ti o sí jẹ àwọn àmì tó fin tóbi jùlọ, ton tọ́ka sí agbára ọba Olùborí, ni àwọn Ìpìnlẹ̀ mẹ́fà ti Allāh tó ga jùlọ ṣe àlàyé rẹ, ni àlàyé ti o ye yékéyéké fun gbogbo èèyàn, ti o kọjá oun ti àwọn ènìyàn nro. Read below or ...

Read moreDetails

Usool us Sittah ni Èdè Yorùbá by Abu Muhsinah As-Salafi

All praise is due to Allāh, the Lord of the worlds. And may He extol the Messenger in the highest company of Angels, and grant him peace, likewise to his family, Companions and those who follow him until the Day of Resurrection. This is the recitation of the text Usool us Sittah in Yoruba. https://soundcloud.com/arrisaalah-media/usul-sittah-yoruba?si=3048e05937d34157822280d6af676871&utm_source=clipboard&utm_medium=text&utm_campaign=social_sharing

Read moreDetails

Àwọn Òfin Mẹ́rin Nípa Ìmú Orogún Pẹ̀lú Allāh

Ni Orúkọ Allāh, Ọba Àjọkẹ‌Ayé, Àṣàkẹ‌Ọ‌run. Mọ nbẹ Allāh, Ọba Ọlọ‌rẹ jùlọ, Ọba alága ọlá to kànkà, ki o mu ọ ni ààyò ni ilé ayé nbi àti ni ọjọ‌ ìkẹyìn, àti wípé ki o ṣe ọ ni oníbùkún ni gbogbo ibí tí o ba wa. Àti wípé ki ó ṣe ọ‌ ni ẹni tí wọn ba fun ni nkan, ti yíò dupẹ, ti wọn ...

Read moreDetails

Àlàyé ránpẹ‌ nípa Bídíàh àti ewu rẹ‌

Ẹ‌yín lè ti máa gbọ‌, tàbí kí ẹti rí bí àwọn Ahlu Sunnah ṣé máa n'kìlò fún àwọn èèyàn kúrò níbi Bídíàh (àdádáálẹ‌ ẹ‌sìn), ṣùgbọ‌n tí ẹ kò mọ ohun tí wó‌n pèní Bídíàh àti ìdí tí wọ‌ n'fín sọ wípé kò da. Gbólóhùn “Bídíàh” jẹ‌ èdè lárúbáwá, tí ìtumọ‌ rẹ‌ jẹ‌ “àdádáálẹ‌ inú ẹ‌sìn”. Ìyẹn ni àwọn ohun tí kò sí lára ẹ‌sìn láyé ...

Read moreDetails

Àwọn Ofin Ipìlẹ ̀Sunnah ti Imām Al-Ḥumaydi

Ni orúkọ Allāh, Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́Ọ̀run.Àwọn òfin ìpìlẹ̀ Sunnah ti Imām Al-ḤumaydiBishr bn Mūsá gba wá fun wa, ó sọ pé: Al-Ḥumaydi gba wá fun wa, ó sọ pé:Sunnah ni ọdọ wa, òhun ni ki èèyàn gbàgbọ́ ninu kádàrá—dáadáa rẹ̀, àti búburú rẹ— dídùn rẹ, àti kíkorò rẹ. Ki o si mọ pé, ohun ti o ba ba, kòsí làkọsílẹ̀ pé yóò tàsé rẹ, ohun ...

Read moreDetails

ʿAqīdah Ar-Rāziyayn Òfin Ìpìlẹ Sunnah àti Àdìsọ́kàn Ẹsìn

Ni orúkọ Allāh O‌ba Àjọkẹ‌ Ayé Àṣàkẹ‌ Ọ‌run Al-Imām Abū Muḥammad ʿAbdurRahmān ọmọ Abū Ḥātim sọ wípé: Mo bi Bàbá mi àti Abū Zurʿah ki Allāh yọnu sí àwọn méjèèjì, nípa àwọn ojúpọ‌nà àwọn Ahl As-Sunnah níbi àwọn òfin ìpìnlẹ‌ ẹ‌sìn àti oun tí àwọn méjèèjì bá pàdé ni ọ‌dọ‌ àwọn oní mímọ‌ ẹ‌sìn ní gbogbo ìlú àti oun tí àwọn méjèèjì ni—ni àdìsọ‌kàn nípa ...

Read moreDetails

Àwọn Òfin Ìpìlẹ̀ Sunnah Ti Al Imām Aḥmad ọmọ Ḥanbal

Ní Orúkọ Ọlọhun, Àjọkẹ́ Ayé, Àṣàkẹ́Ọ̀run. Al-Imām Aḥmad ọmọ Ḥanbal kí Ọlọhun kẹ́ wọn sọ wípé: Àwọn òfin ìpìlẹ̀ Sunnah ni ọ̀dọ wa, òhun ni gbígbá ohun ti awọn Ṣaḥābah òjíṣẹ́Ọlọhun ﷺwa lórí rẹ̀ mú, àti títẹ̀lé wọn — ni tii àwòkọ́ṣe, àti gbígbé Bidʿah— ìyẹn àdádáálẹ̀ jù sílẹ̀ , àti pé, gbogbo bidʿah jẹ anù. Read below or download eBook PDF here. Download here

Read moreDetails

Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Láti inú Ìtàn Ikú Abu Tālib, Ẹ̀gbọ́n Bàbá Ànnábí (ﷺ)

Abū Tālib jẹ́ ẹ̀gbọ́n bàbá Ànnábì ﷺ, tí ó sì nífẹ Ànnábi ﷺ lọ́pọ̀lọpọ̀. Nígbàtí àsìkò ikú Abū Tālib tó, Ànnábi ﷺ lọ sí ọ̀dọ rẹ̀ láti pè wípé kí ó gba Islam kí ó tó kú, Ànnábi sọ fun wípé, “Ìrẹ ẹ̀gbọ́n bàbá mi, sọ wípé “Lā ilāha illa Llāh”, ọ̀rọ̀ tí màá fi ṣe ẹ̀rí fún ọ ní iwájú Allāh”. Ṣùgbọ́n kàkàkí Abū ...

Read moreDetails

Yorùbá Translation of Nawaaqidul Islām | Abu Muhsinah As-Salafi

All praise is due to Allāh, the Lord of the worlds. And may He extol the Messenger in the highest company of Angels, and grant him peace, likewise to his family, Companions and those who follow him until the Day of Resurrection. This is the recitation of the text with Nawaaqidul Islām Yoruba translation. https://soundcloud.com/arrisaalah-media/yoruba-translation-of-nawaaqidul-islam-abu-muhsinah-as-salafi?utm_source=clipboard&utm_medium=text&utm_campaign=social_sharing

Read moreDetails
Page 1 of 6 1 2 6

Categories

Donations

Help our organization by donating today! All donations go directly to making a difference for our cause.